Ki lo gbayi bi aso ibile wa? Posted by: oodua in Àṣà Oòduà, Ẹṣọ Aṣọ Ajeji, Iroyin Pajawiri 0 Aso to fi iwa omoluabi han to si rewa loju; aso to ponni le, aso tomo le jogun lowo eni. Ninu maaki mewaa (10), meloo le fe fun baba atomo re nipa imura won? Aso 2015-12-14 oodua tweet