Home / Àṣà Oòduà / Linda Ikeji àti omo rè, tí orúko omo náà n jé Jayce Jeremi nínú àwòrán tuntun.

Linda Ikeji àti omo rè, tí orúko omo náà n jé Jayce Jeremi nínú àwòrán tuntun.

Gbajúgbajà elétíofe tí gbogbo ayé mò sí Linda Ikeji tí ó sèsè bí omo okúnrin rè ní ojó ketàdínlógún osú kesàn-án odún tí a wà yí, pín àwòrán sí orí èro insítágírámù pèlú omo rè, Jayce.

Ó ko síbè wípé…
“Mo gbàdúrà wípé kí gbogbo obìnrin di abiyamo…kò sí ayo tí ó tó èyí”.

About Awo

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...