Home / Àṣà Oòduà / Ni ale ojokan ojise Eledumare kan nlo….

Ni ale ojokan ojise Eledumare kan nlo….

ale

Ni ale ojokan ojise Eledumare kan nlo
si ile ijosin lati lo josin nigba ti o
nlo ni moto re ba taku ti kosi rise
titi asiko filo ni o ba pinu lati sun
sinu moto ki o fi di ojo keji ni
igba ti odi dede ago meji ni
arakunrin yi ba dide lati se adura
ni o wa n wo ina ninu igbo ti o si
lo sibe ti osi ri awon kan ti won
so ewure mole ti won n sepe fun
pe ko ni gbe nkan rere se nile
aye re wipe ati pe ninu inira ni o
maku si wipe ipin rere ti oyan lati
orun ko ni di mi muse ninu aye
re bi won se lo tan ni emi olorun
sofun ojise yi pe ki ose adura fun
eran yen wipe tori e ni ohun se
jeki moto e baje ni igba ti ojise yi
bere adua ni eran yen di eyan,
mo fi akoko yi gba ni adura pe
gbo gbo ete ota lori aye mi tio so
pe ipin rere ti mo yan lati orun ko
ni di mimu se ninu aye mi oluwa
bami so ete won di ofo, oluwa
gbo gbo eni ti abi lati ara obinrin
ti o fe ma da aye mi lamu to ni
kin sise bi erin kin ma je ije eliri
oluwa bami gba agbara lowo
won kin le ri aye se rere, kin ma
ba won wa aye asan (Ase)

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*