Home / Àṣà Oòduà / O pari!!!

O pari!!!

 

-Ibanuje aye e pari loni
-Ekun ose aye e pari loni
-Ait’egbe aye e pari Lati eni lo
-Iya e pari lati oni lo
-Asedanu aye e pari lati oni lo
-o tun r’arun owo mo lailai
-O koni fosi logba
-Owo,alaafia, ayo, omo, ise kekere owo nlanla ni ko maa ya s’odo e
-Okan re yio bale
-Kio ma se rago laye
-O ma dagba, o koni dagba OSI. Ase!!!!

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

tems

Mo setán láti kú’ – Tems

Mo setán láti kú’ – Tems Mary Fágbohùn Olorin Naijiria olugbafe eye Grammy, Temilade Openiyi, ti a mo si Tems, ti safihan pe oun setan lati doju ko saare nigba ti oun fi eya orin takasufe ti gbogbo eniyan mo kaakiri orile ede sile fun R&B. Tems wi pe oun ni igbagbo pupo ninu ara oun to bee ti oun ko bikita bi oun o ba “je nnkankan tabi da enikeni” pelu R&B. Olorin ‘Essence’ naa so pe oun kan ...