Home / Àṣà Oòduà / Obàtálá

Obàtálá

Obàtálá

(Ìwà)

Amúyan abìtanná yanranyanran
Adia’fun orunmila babá o tanná fórìsà riwa
Ebo lawo ni kose
Ógbébo órúbo
Ógbèrù ótèrù
Njé ifá tan sílé, èdú tan sónà
Tan ni o mòpé ina ire lope ntan

Bàbá arúgbó that:
Sleeps in purity
Rise in purity
The great craftman that mould
eminence into human beings
The most purity that dwell in white

#Oturupon_rosun

Òrìsà májekí ìwà mi o bàjé…Àsē o
-Awo

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Oríkì Obàtálá

Ọbàtálá ọbátárìsàỌba pátápátá tí ń bá wọn gbóde iránjéỌba nílé Ifọ́nÒ sùn nínú àlàÒ jí nínú àlàÒ tí inú àlà dìdeÒrìṣà wun mi ní budoIbi Ire l’òrìsá kalẹ Akú òsè Obàtálá O kettle drum