Home / Àṣà Oòduà / Odu Ifa Owonrinpota/ Osa

Odu Ifa Owonrinpota/ Osa

| |  | |
| |   |
 |     |
 |     |

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi ana, a sin ku imura ise oni, Eledumare yio jeki ose yi je ose ayo ati idunnu funwa o ase.
Odu ifa OWONRINPOTA/ OSA lo gate laaro yi, ifa yi fore orire nla fun akapo ti odu ifa yi ba jade si, ifa ni oore idunnu nla kan nbe niwaju akapo yi ti yio jifa re lofe lofo bi akapo yi ba le rubo daradara.

Ifa naa ki bayi wipe, Owonrin gansa gansa a difa fun Orunmila lojo ti baba yio ji ni kutukutu owuro ti yio ri owo gbe, won ni ki baba karale ebo ni ki o wa se nitori ki o baa le jifa owo nla kan, obi meji, eyele funfun, agbebo adiye, eru isu, eku emon, eja aro gbigbe ati igba ewe ayajo ifa, Orunmila si kabomora o rubo won si se sise ifa fun won si sofun wipe ki o maa sin eyele to fi bofa yen, nigbati o di laaro kutukutu ojo meji seni Orunmila ji wipe ki oun lo ki awon Omo irunmole ore oun, nibiti o ti nlo se lo nwo ibiti aso ti nfun rururu nigbati o maa debe to tu aso naa seni baba ba otiti baba aje odigbara baba okun nibe Orunmila wa gbe o gbe pamo sibiti o lowo o wa pada sile lati lo beere lowo oke iponri re boya nkan owo ti oun maa le gbe ni oke iponri re si sofun wipe oore ti Eledumare talaari si Orunmila ni, Orunmila wa pada o lo gbe owo wale baba wa di olowo o di oloro o wa njo o nyo o nyin awo awon awo nyin ifa, ifa nyin Eledumare oni nje riru ebo a maa gbeni eru arukesu a maa da ladaju nje ko pe ko jina ifa wa bami ni jebutu ire nje jebutu ire ni a nba awo lese obarisa.

Eyin eniyan mi, mo gbaladura laaro yi wipe ibikibi yio wu ki aje fara pamo si Eledumare yio da ese wa kobe, gbogbo adawole wa loni yio mu opolopo ire aje jade, ori wa yio gbewa debi ire ako ni se alaini ohun rere, gegebi oni se je ojo aje, aje yio bawa gbe ao raje fi sokun ao raje fi sede o aaaseee.
ABORU ABOYE OOO.

English Version:

Good morning my people, how was your night? Hope it was greatly enjoyed, I pray that this week will be a week of great joy for us ase.
It is OWONRINPOTA/ OSA corpus that revealed this morning, ifa foresee blessing for whoever this corpus revealed out for, ifa said he/she will be very fortunate to meet a great opportunity in his/her life if a sacrifice can be well offered.

Hear what the corpus said: Owonrin gansa gansa cast divined for Orunmila when father would wake up early in the morning and be lucky to meet plenty of money, Orunmila was advised to offer sacrifice so that he may be fortunate to meet a wealth by the road side, two kola nuts, white pigeon, hen, yam brown mouse, fish and ifa leaves, also he was instructed to be rearing that pigeon after it was using to feed ifa and he complied, when it was second day, Orunmila woke up early in the morning to greet his member of deities and he found out that something was on the road side covered by white cloth and he went there to check what it is and fortunately he found out it is a plenty of money, Orunmila carried it and kept it securely somewhere and he went back home to ask from his oke iponri whether he should do away with the money or not, but luckily oke iponri made him understand that the money is for him and he went back to carry it this is how Orunmila became rich, he started dancing and rejoicing praising priest the priests were praising ifa while ifa was praising Eledumare.

My people, I pray this morning that wherever places that wealth is been kept Eledumare will direct us there, anything we lay our hands on today will yield a lots of money, we shall never lack, our heads will be fortunate to meet good things, as today is a day of wealth, may we have money to do all we needs ase.

Faniyi David Osagbami

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

ifa

Kùtùkùtù Ìrèní Laó He Erè Nígbódù Oòni

Òní laó roko létí opónÒla laó sákà lágbèrùKùtùkùtù ìrèní laó he erè nígbódù oòniKáyáa múlé pontíKámú òdèdè rokàKáfi agbada dínranÀwèje wèmu nípón omodé wòyí lójúÒrìsà lópabuké tánLódákún sábaro nídìíOmo-ojo húnsáré gíríjo-gíríjoOmo-ojo húnsáré gìrìjo-gìrìjoIlé-ifón kògba obàtáláÈlàgboro kògba òrìsàOjúgboro ni tàfínÈlàgboro ni tòrìsàOmi níti ojú-omi rúwáÈròyà wáàponÈròyà wáàmuRúkú-rùkù-rúkú niwón nse lókè ohùnkòErú kùnrin won nííjé bánakúErú bìnrin won nííjé wòrúkúDimúdimù aleìgbòOkùnrin yàkàwú orí ìgbáÌgbá kòwóOkùnrin yàkàwú kòsòkalèÒní laóko igbó olú-kóókó-bojoÒla laóko igbó olú-kóókó-bojoAkogbó olú-kóókó-bojo tánApa ekùn kan mìnììjò-miniijo tínbe lábé ìtíWónní kí ...