Home / Àṣà Oòduà / Oko Ofurufu Helicopter Ti Awon Omo Ologun Ti Jalule Ni Ilu Kaduna

Oko Ofurufu Helicopter Ti Awon Omo Ologun Ti Jalule Ni Ilu Kaduna


Oko ofurufu helicopter eleyii ti awon ologun n lo fun idanileko lo jabo ni ibuba awon omo ologun to wa ni Kaduna leyin iseju mewaa to gbera soke.

Ilu Abuja lagbo wi pe oko ofurufu naa n lo ki lala re to lo soke to pada wale loju kan naa mbe.
Gege bi itopinpin Olayemi Oniroyin, awon eniyan bi meje ti won wa ninu baalu naa la gbo wi pe won parun.

E ku etileko fun akotun iroyin.

Orisun Iwe Iroyin

About Lolade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...