Home / Àṣà Oòduà / Osise Arik Airline Ba Naija Loju Je Niluu London: Won Ka “Lafun Funfun Alata’ Mo o Lowo

Osise Arik Airline Ba Naija Loju Je Niluu London: Won Ka “Lafun Funfun Alata’ Mo o Lowo


Owo ti te CHIKA EGWU UDENSI, okan ninu awon osise ile ise oko ofurufu ARIK Airline ni papako ofurufu HEATHROW ti ilu London pelu ogun oloro kokeeni.

Ogun oloro ti won ka mo bobo naa lowo ni won ni iye owo re yoo to nnkan bi ogorun milionu owo naira.

Oruko Nigeria ti emi n gbiyanju lati tun se ni awon kan si n gbinyaju lati maa yimo inu erofo loju awon ebo.

Laaarin emi ati CHIKA EGWU UDENSI ija sese bere ni o.

About oodua

2 comments

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...