Home / Àṣà Oòduà / Omokùnrin kan tí orúko rè ńjé Charlyboy subú lulè nígbà tí won ń se àtakò Buhari. 

Omokùnrin kan tí orúko rè ńjé Charlyboy subú lulè nígbà tí won ń se àtakò Buhari. 

 Àmóhùnmáwòrán Channels ti pín fídíò tí ó se àfihàn omokùnrin kan tí ó ń jé Charlyboy nígbà tí ó subú lulè nígbà tí won ń tako Buhari lówó ní ìlú Abuja láàárò òní. Àwon Agbófinró fín tajútajú àti omi láti tú àwon tó ń tako Buhari tí won sì fé kí ó ko ìwé fi ipò sílè tàbí kí ó dé láti ìlú òyìnbó tí ó ti wà láti bí ojó méjìléláàádòrún (92 days) séyìn : e wo fídíò ní ìsàlè….

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...