Home / Àṣà Oòduà / Onka ede Yoruba 100 – 20,000

Onka ede Yoruba 100 – 20,000

1,000-Ẹgbẹrun, ẹgbẹ̀rún
1,100-Ẹgbẹrunlelọgọrun
1,200-Ẹgbẹfa, ẹgbẹ̀fà
1,300-Ẹdẹgbeje
1,400-Egbeje, egbèje
1,500-Ẹdẹgbẹjọ
1,600-Ẹgbẹjọ, ẹgbẹ̀jọ
1,700-Ẹdẹgbẹsan
1,800-Ẹgbẹsan, ẹgbẹ̀sàn
1,900-Ẹgbadinọgọrun

2,000-Ẹgbàwá, ẹgbẹ̀wá, ẹgbàá
2,200-Ẹgbọkanla, ẹgboókànlá
2,400-Egbejila
2,500-Ẹgbẹtaladinlọgọrun
2,600-Ẹgbẹtala
2,800-Ẹgbẹrinla
3,000- Ẹgbẹteedogun, ẹgbẹ́ẹdógún
3,500-Egbejidilogun-din-ọgọrun
4,000-Ẹgbaji, ẹgbàajì
4,500-Ẹgbẹtalelogun-din-ọgọrun
5,000-Ẹdẹgbata, ẹgbẹ́ẹdọ́gbọ̀n
5,500- Ẹgbẹtalelogbọn-din-ọgọrun
6,000-Ẹgbata, ẹgbàáta
7,000-Ẹdẹgbarin, ẹ̀ẹ́dẹ́ɡbarin
8,000-Ẹgbarin, ẹgbàárin
9,000-Ẹdẹgbarun, ẹ̀ẹ́dẹ́ɡbàárùn
10,000-Ẹgbarun, ẹgbàárùn
16,000 – Ẹgbajọ, ẹgbàájọ
20,000: Ẹgbawa, ẹgbàawǎ tabi ọkẹ́ kán

About BalogunAdesina

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...