Oritsefemi àti àwon òré rè ti dòbálè níwájú àwon ebí ìyàwó rè tí a mò sí àna rè níbi ìgbéyàwó náà, ìgbéyàwó náà dára púpò.
N se ni ó dàbí kí èmi náà lo se ìgbéyàwó báyìí.
Home / Àṣà Oòduà / Oritsefemi dòbálè ní iwájú àwon àna rè, àwon òbí Nabila Fash níbi ayeye ìgbéyàwó ìbílè won.
Tagged with: Àṣà Yorùbá