Home / Àṣà Oòduà / Ori Eni Lawure Eni O – Iyalorisa Omitonade Ifawemimo

Ori Eni Lawure Eni O – Iyalorisa Omitonade Ifawemimo

Ori Eni Lawure Eni O
Ori Eni Lawure Eni
Mo ji lowuro mo dewo mori O
Ori Eni Lawure Eni…
Ki Ori wa ma sowa nu ooo… Ase Ire O!
Translation
One’s Spiritual/Inner head is his/her super spell(2ce)
I woke up in the morning and held my head
One’s Spiritual/Inner head is his/her super spell
May our Spiritual/Inner head do not lead us astray… Ase Ire O!!!

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo