Home / Àṣà Oòduà / Ori mi Apeere

Ori mi Apeere

Ka ji ni kutukutu
Ka mu ohun ipin ko’pin
d’Ifa fun Olomo-ajiba’re-pade
Emi ni mo ji ni kutukutu ti mo f’ohun ipin ko’pin
Emi ni mo ba ire pade nigba gbogbo

ori mi apeere
Ateteniran
Atetegbeni ju Orisha
Ko si Orisha ti danni gbe leyin ori eni
Ori eni ni seni de ade owo
Ori eni ni seni tepa ileke
Ori wo ibi rere Simi de
Ese wo ibi rere Simi re
Ibi ti ori mi yio ti suhan ju bayi lo
Ori mi Simi de ibe

About ayangalu

x

Check Also

Yemọja

ÉÉPà Omi O!!!grand Finale, Yemọja ÒGùnlẹ́kí – Pópó Yemọja, Ìbàdàn

A dúpẹ́ púpọ̀ lọ́wọ́ Baálẹ̀ Yemọja, Ìyá Omítọ̀nàdé, Ẹbí, Ará, gbogbo Àgbà àti Ọmọdé… Ìbà Olódùmarè, ọdún pé, ọdún jọ. .To all friends, fans and well wishers, we’re grateful.