Home / Àṣà Oòduà / Oro Sunuku

Oro Sunuku

Moki gbogbo wa ku ise oni, asejere ni gbogbo wa yoo se lagbara Eledua ase. Eyi ni lati fi to gbogbo a wa ololufe eto yii leti wipe, gbakogbi itan akakogbon ti a npo po ti di itan agbeleka fun gbogbo wa lati ola lo. ……..Akole itan naa ni. ORE MI, mo wa ngba ladura fun gbogbo wa wipe, Oba mi Eledua ko ni se wa ni emi ti ko ni dola to n da ipariosu ase.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo