Home / Àṣà Oòduà / Owó Sìkún Àwon Olóòpá Te Arákùnrin Tí Ó Máa Ń Jí Okò Gbé Ní Yenegoa. 

Owó Sìkún Àwon Olóòpá Te Arákùnrin Tí Ó Máa Ń Jí Okò Gbé Ní Yenegoa. 

Nígbà tí won ti mu fún èsùn kan náà.
Arákùnrin tí ó wà nínú àwòrán ní ìsàlè yìí tí ó yan isé okò jíjígbé láàyò ni owó sìkún àwon olóòpá bà ní Yenegoa, ní ìjoba ìpínlè Bayelsa fún ìgbà keta.

Gégé bí ìròyìn se so owó àwon olóòpá ti te afurasí yí rí ní Yenegoa  àti port Harcourt fún èsùn kan náà sùgbón tí ó máa ń bó ní àgo àwon olóòpá.
Ní àkókò yí, ó tún ti bó bí ó se máa ń bó. Àwon olóòpá sì ti búra láti sìn ín dé bèbè èwòn.,..

English version
Continue after the page break.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo