Gbajúgbajà ni, òtòkùlú ni, captain Tunde Demuren tí ìnagije rè n jé OAP, oko toolz ti gbé lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán yí nígbà tí won wo okò òfurufú lo sí Capetown láti péjú pésè níbí ayege ìgbéyàwó aláréde ti Banky W àti Adesua Etomi.
Home / Àṣà Oòduà / Tunde Demuren, Ebuka àti ìyàwó rè ti wo okò òfurufú (jet) láti lo sí ibi ìgbéyàwó Banky W.
Tagged with: Àṣà Yorùbá