Home / Àṣà Oòduà / Won ti ojà ní Abeokuta láti fi se àpónlé fún Oba won tí ó di olóògbé.

Won ti ojà ní Abeokuta láti fi se àpónlé fún Oba won tí ó di olóògbé.

Ojà tí ó wà ní ìlú Abeokuta ní won tì pa pátápátá ní àná, won se èyí láti fi se àpónlé Oba won tí ó wàjà eni tí a mò sí Oba Halidu Laloko (MFR) tí ó jé Agura ti Gbagura tí ó papòdà láti lo bá àwon baba ńlá rè ní ojó kejìlá osù keje odún 2018 (12/07/2018).
Èyí fi hàn wípé Àsà Yorùbá kò le parun.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo