Home / Àṣà Oòduà / “Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo….

“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo….

“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo
Wun ó bí’mo lé’mo n tó máalo
Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo
Bí Wón n n’íre lórun èmi ò mò
Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo
I will have enough wealth before going back
I will have lot of children before going back
I will have lot of blessing before I go back
I don’t know if I will be privileged to have such in heaven
I will have lot of blessing before I die.
I pray to Ifa that we will all acquire all the good things we want in our life before it’s time for us to go back. Ase!!!”
-Sacred Odu Eji Ogbe-
~Owo

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo