Home / Àṣà Oòduà / Yoruba Bo Won Ni Agbomojo Lomo N Moju…

Yoruba Bo Won Ni Agbomojo Lomo N Moju…

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Ido Alayo ti ose yi. E wa nkan f’idi le abi ki e f’idi le nkan ki a jo gbadun ara wa bii ti ateyin wa.

Lori eto toni ibeere kan ni a o fi ko ara wa logbon, idaun wo ni eyin ni si ibeere yi, oju wo ni eyin fi wo ihuwasi si, ipa wo ni oro yi ko lodo tiyin, ki ni amoran yin fun awon ti won wa niru ipo be?

Yoruba bo won ni AGBOMOJO LOMO N MOJU, e wo aworan arakunrin isale yi daradara, oju wo ni eyin fi wo ere ti arakunrin yi n ba omo yi se? Ki ni eyin le so nipa iwa yi? Awon kan wi pe:-

…… KO SOHUN TO BURU NIBE

……EWU N BE NIBE

……EREKERE NI

…… AYE N SERU E

E je ki a gbo ero tiyin lori oro yi ki a jo ko ara wa logbon tori ogbon o pin sibi kan.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo