Home / Àṣà Oòduà / Aare Ilu South Africa Ti Sofin Lati Maa Sami Si Oju Ara Awon To Ba Ni Kokoro HIV

Aare Ilu South Africa Ti Sofin Lati Maa Sami Si Oju Ara Awon To Ba Ni Kokoro HIV

Aare ilu South Africa, Jocob Zuma, ti fi owo si abadofin lati maa sami si egbe kan oju ara awon ti won ba ni kokoro HIV lara. Won ni nipa sise eleyii, yoo mu adinku ba awon eniyan ti won ko kokoro naa.  Won si ro awon eniyan bi milionu mewaa eleyii ti ayewo ti fi han wi pe won ni kokoro naa lara lati wa gba amin naa, eleyii ti won se bi tattoo.   Bakan naa ni won se ileri ebun owo fun awon to ba yoju

 

Orisun

About Lolade

One comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*