Home / Àṣà Oòduà / Adajo Ti Dajo Iku Fun Omobirin To Gbe Ogun-Oloro Pamo Si Oju-Ara Re Ni Ilu Thailand

Adajo Ti Dajo Iku Fun Omobirin To Gbe Ogun-Oloro Pamo Si Oju-Ara Re Ni Ilu Thailand


Ile ejo ti dajo iku fun Chonmanee Laphathanawat, eni ogbon (30) odun ni ilu Thailand pelu esun gbigbe ogun oloro cocaine ni orileede Thailand.

Omobirin yii ni won mu pelu bo se sin ogun-oloro ti won ti ro sinu kapusu (capsules) bi aadorin (70) si oju-ara ati inu iho idi re.

Ana, 27-08-2015, ni won da ejo omobirin naa.

Ki Oluwa oba dari gbogbo ese re jin-in.

E sora fun ogun-oloro. Ko Dara!

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

seun kuti

Orí kó Seun Kuti yọ kúrò lọ́wọ́ ikú ní yàrá ìgbàlejò US

Mary Fágbohùn Olórin Afrobeat Seun Kuti ti fi ìrírí ibanuje ọkàn rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà han nígbà tí ọta ibọn kan gúnlẹ̀ lójú fèrèsé yàrá igbalejo rẹ̀. O salaye ibapade to ba ni lẹru naa lori oju-iwe Instagram rẹ, o fi fidio ferese ti ọta ibọn naa bajẹ ati iho re han. Seun, ẹni ti o ṣalaye iyalẹnu, beere iwoye ti aabo ni Amẹrika. Ninu fonran naa, Seun Kuti sọ pe oun wa ninu yara igbalejo, ti oun n sinmi, ...