Home / Àṣà Oòduà / Awon Omo Ologun Ile Nigeria Fi Emi Awon Omo Boko Haram Ti Won Woso Ologun Sorun Sofo Bi Omi Efo

Awon Omo Ologun Ile Nigeria Fi Emi Awon Omo Boko Haram Ti Won Woso Ologun Sorun Sofo Bi Omi Efo


Asiri awon omo Boko Haram kan ti won wo aso ologun sorun sise buburu owo won ti tu ni apa ila oorun-arewa ile Nigeria.  Awon omo Ologun Nigeria yosi won ni ibuba won ti won go si, won si se won sibalasibolo. Oku awon omo Boko Haram si lefo sori ile bi oku aja.

Olayemioniroyin

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...