Home / Àṣà Oòduà / Odó kàyééfi ńlá tí ó wà ní *ADO AWAYE*.

Odó kàyééfi ńlá tí ó wà ní *ADO AWAYE*.

Ìlú kéréje kan wà ní ìpínlè Oyo tí orúko ìlú náà sì ń jé *ADO AWAYE*, òdó kàyééfi kan wà ní ìlú yí tí ó jé wípé bí ènìyàn bá ti esè kan bo inú rè yóò fa eni náà tí a kò sì ní mo ibi tí eni náà ma jásí.

Bí ènìyàn bá bu omi òdó yí tí ó se àdúrà si tí ó sì mun-ún gbogbo ohun tí ó bá toro ni yóò rí béè. Orúko odò náà ni *ODÒ ÌYÀKÉ*

Àwòrán odò náà rè é n’ísàlè…

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára