Bí omo eni bá dára kí á wí, Akékòó gboyè ti ìmò tí ó n se ìtòjú ènìyàn tí a mò sí Medical Student, ti gba èbùn pàtàkí tí a mò dí Okò bògìnì àti owó goboi.
Esther Azom ni orúko akékòó yí njé, a gbó wípé okò afé tí won fún náà kojá Mílíónù lónà márún-ún àtiwípé Ooni ti ilè ifè fún arábìnrin náà ni àádótá-lé’rúgba (#250, 000) tí àpapò owó tí ó sì gbà jé (#750, 000).
Home / Àṣà Oòduà / Akékòó tí ó se dáradára jùlo ní ilé-èkó gíga tí a mò sí ABUAD gba èbùn nlá fúm oríre yí.
Tagged with: Àṣà Yorùbá