Léyìn àrídájú tó ji-n-gí-ri, mo le f’owó s’òyà pé pé ilé-èkó Nwafor Orizu College of Education Nsugbe ti pàdánù tí ó pò .
Arákùnrin Mr Osaji Charles, tí ó jé Mr NASELS télè (2013/2014 session), ni won yín ìbon fún tí a kò sì mo eni tí ó yin ìbon náà níbi tí kò jìnà sí “ota Queen “. Mr Don Charles, bí ó se dáhùn lórí èro ayélujàra (facebook), ó ye kí ó parí ìdánwò àsekágbá ti eka-èkó rè ní ojó etì ojó ketàlélógún osù keje odún tí a wà yí (21st of July) tí ó sì ye kí o se ayeye ìkékòó jáde ní ojó karùndínlógbòn (25th) nígbà tí ó ti parí gbogbo ohun míràn tí ó ye kí ó se.
A bá gbogbo ìdílé Osaji kédùn, pèlú àwon akékòó eka-èkó èdè gèésì English department NOCEN, pèlú gbogbo àwon ilé-èkó t’ókùn ní agbègbè náà. Àkókò yí ni inú wa bàjé púpò .
Sùn -un re oooo
Continue after the page break for English Version
Pages: 1 2