Home / Àṣà Oòduà / Èsì ìdánwò alásekágbá ilé-èkó girama (waec)tí ó burúkú jù nínú odún 2017, tí a rí he. 

Èsì ìdánwò alásekágbá ilé-èkó girama (waec)tí ó burúkú jù nínú odún 2017, tí a rí he. 

Láàrin ogún-l’ógbòn àwon akékòó tí ó tó 1,559,162 tí won jòkó fún ìdánwò àsekágbá ilé -èkó girama tí a mò sí waec ní odún 2017 tí ó jé wípé òpò ni a ti rí, tí ó sì dára …
Akékòó tí ó tó 926,486 ni won gba àmì C tí a mò sí credit Ókéré jù nínú isé bíi márùn-ún tí English- language àti Mathematics wà lára rè, bí àwa se ri, ohun tí a rí ni wípé ó dára ju odún kan àti kejì séyìn lo. Tí a sì gbé òsùwòn le tí ó tó 59.23% tí ti odún tí ó lo sì jé 52.9% àti èyí tí ó lo l’ódún méjì séyìn sì jé 38.7% . Látàrí eléyìí, èyí jé kí ó di mímò wípé odoodún ni yóò ma dára si àtiwípé ó tún máa jé kí òpòlopò omo se àseyege, tí won bá le tèsíwájú láti sisé kárakára, tí won sì fi gbogbo ara si, tí won sì ní ìpinnu tí àwon olùkó won kó won dáadáa, tí agbègbè àti àwon olólùfé won sì gbárùkù tì wón, mi ò rí ìdí kankan tí won kò fi ní yege.
  Nígbà tí àkókó rí èsì ìdánwò yí, awá rò wípé kò sí ìdí kan tí ó ni kí akékòó tí ó ti gbáradì fún ìdánwò dáadáa máa tiraka láti ní irú èsì ìdánwò tí ó dára báyìí…

Continue after the page break for English Version

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo