Home / Àṣà Oòduà / Alex Asogwa di onílè púpò ní Omo odún méjìlélógún (22).

Alex Asogwa di onílè púpò ní Omo odún méjìlélógún (22).

Ará ilé Big Brother Naija télè tí a mò sí Alex Asogwa tí ó sèsè towó bo ìwé pèlú ilé-isé tí ó n ta ilè tí ó tún ń ta Ilé, ilé-isé real estate and investment company.Alex Asogwa ti gbe lo sí orí èro ayélujára láti dúpé lówó olórun, nítorí kìí se onílè eyo kan bí Kò se púpò, nígbà tí Kò sì ju omo odún méjìlélógún Lo.

 

About Awo

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...