Home / Àṣà Oòduà / Arábìnrin kan ni ó bí ìbeta léyìn odún métàdínlógún tí ó tí se ìgbéyàwó.

Arábìnrin kan ni ó bí ìbeta léyìn odún métàdínlógún tí ó tí se ìgbéyàwó.

Arábìnrin kan ni ó gbe lo sí orí èro ayélujára tí a mo sí facebook láti lo pín ìròyìn ayò wípé òhun bí ìbeta láti bí odún métàdínlógún sèyìn. Ó ko síbè wípé…
” èyin abiyamo mi ò le mú ayo náà móra rárá, ègbón mi bí ìbeta ní àná léyìn odún métàdínlógún tí ó ri se ìgbéyàwó. E jòwó e bámi pín ìròyìn ayò yí.

About Awo

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...