Arábìnrin yí ni ó jí èro ìbánisòrò ogbòn (30) tí ó sì ko pamó sí inú kómú àti pátá rè.
Odóbìnrin tí a kò mo eye tí ó su ú, ni ó jí ju èro ìbánisòrò ogbòn lo tí ó sì fi pamó sí inú kómú àti pátá rè tí owó pálábá rè sì ti ségi ní ilé-ìtajà kan.
A kò tilè mo ibi tí ìsèlè náà ti selè sùgbón àwòrán yí nítorí ó yani lénu.
Home / Àṣà Oòduà / Arábìnrin yí ni ó jí èro ìbánisòrò ogbòn (30) tí ó sì ko pamó sí inú kómú àti pátá rè.
Tagged with: Àṣà Yorùbá