Taloye kogba eni ti o dara ju ninu awon osere meji yii ?
Taloye kogba eni ti o dara ju ninu awon osere meji yii ?
Tagged with: Femi Adebayo Odunlade Adekola
*Femi Adebayo n wonu oselu lo diedie Nibayii, gomina ipinle Kwara, Abdulfatah Ahmed, ti yan ogbontarigi onisetiata, Femi Adebayo, gege bi oluranlowo pataki nipa ise ona, asa ati irinajo-afe (Special Assistant on Arts, Culture and Tourism). Osere ti inagije re tun je Jelili ko le pa ayo naa mora pelu bo se kede iyansipo re naa lori ayelujara fun awon ololufe re pata. Bakan naa lo tun un dupe lowo gomina ipinle Kwara fun anfaani ti won fun un lati ...