Home / Àṣà Oòduà / Arewa Asa Toni: 17-04-2016 Ogbeni/Alaji Taiwo Hassan (Ogogo)

Arewa Asa Toni: 17-04-2016 Ogbeni/Alaji Taiwo Hassan (Ogogo)

Arewa asa wa toni ni Alhaji Taiwo Hassan, abi won
ni Ilaro ni odun 1959, baba tobi won ibeji ni, baba
tobi baba won ibeji ni, emerin ototo ni won ti bi ibeji
ninu ile won,  Won losi ile-we alakobere christ Church School
towa ni Ilaro nipinle ogun, leyin igbayen ni won losi
ilu Eko nibe naa ni wonsiti pari iwe alakobere won,
leyin nani won losi ile-we(technical School) lati lo
ko ise atun okose (Automobile Mechanic) leyin nani
won tesiwaju pelu sise pelu awon ajo olomi ero
(water coperation) tilu eko fun odun metala
(13years) nigbati odi odun 1981 ni won darapo mo
ise ere ori tage opolopo sinima ni wonti bawon kopa
ninu re, opolopo sinima lawon naa siti gbe jade,
beesini opolopo Ami eye ni wonsi tifi dawon lola pelu

About ayangalu

7 comments

  1. ogogo omokulodo omo ku lomi lomi

  2. Ajepe aye oooo. Opolo yin ko ni joba o

  3. Emi gigun ati alafia ni emafilo ile aiye yin oo

  4. Eku eto o,Olohun a ma lekun imo yin o, Ogogo omo kulodo a ri yin pe o, Ase

  5. Ewa yin o ni baje Ogogo Omo kulodo ajepe aye

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...