Bánà Omo Egbé APC tí ó n lo fún Gómìnà ìpínlè Kwara ni won lè sí iwájú agboolé àwon Saraki.
Ìròyìn kàyéfì…
Omo egbé APC tí a mò sí Abdulrasaq Abdulrahman, tí ó n díjé fún ipò Gómìnà ìpínlè Kwara ti se bánà tí ó pò won sì ti rò wípé bí ó ti tó àti bí ó ti ye ni ó ye kí àwon pín bánà tí àwon ti fi owó tè káàkiri, ni won bá lè sí agboolé àwon Saraki tí ó jé alátakò won..
Home / Àṣà Oòduà / Bánà Omo Egbé APC tí ó n lo fún Gómìnà ìpínlè Kwara ni won lè sí iwájú agboolé àwon Saraki.
Tagged with: Àṣà Yorùbá