Banky W àti Adesua Etomi ya àwòrán pèlú àwon òbí won níbi ìgbéyàwó alárédè won.
Tokotayà tuntun, Banky W àti Adesua Etomi pèlú ègbón Adesua Etomi okùnrin, ìyá rè àti àwon òbí oko ní apá òtún èyí ma tún dára Ooo.
Àwon òbí tí inú won n dùn náà kò yunra láti bá àwon omo won yà àwòrán.
Tagged with: Àṣà Yorùbá