Awon foto re wa nisale
Opolopo ni i pokiki Olajumoke Orisaguna omo oniburedi gege bi oloriire ti Edumare da lola ojiji pelu bo se se alabapada agbaoje ayaworan ati olorin ti n je TY Bello. Laaarin iseju kan, omo oniburedi di orekelewa oba onise oge. Aimoye awon ile ise alaso oge ni won ti bere si sanwo tabua fun un latari igbelaruge ati ipolowo ti n se fun awon oja won. Okan ninu awon banki igbalode tile ti yan gege bi asoju won eleyii ti ...