Eyi ni lati sofun yin wipe anwa arakunrin kan ti oruko re nje Mukaila,ti o je onisowo eran maalu ni onibuore ni agbegbe iyana church ni ilu Ibadan.
Arakunrin yi ni awon kan pe lati ori ero ilewo re lati bii ojo marun seyin,wipe kowa bawon ra eran maalu,won si gbe si inu motor won,lati ojo naa ao tii foju kan okunrin naa titi di wakaati yi. Mo gba lase ki Eledumare bawa wa okunrin naa ri ooo.Koluwa maa so wa