Home / Àṣà Oòduà / E wa wo ohun ti oludije ipo gomina n se lagbala pelu aya re.

E wa wo ohun ti oludije ipo gomina n se lagbala pelu aya re.

Eng Seyi Makinde, okan ninu awon oludije ipo gomina nipinle Oyo, labe egbe oselu SDP ninu eto idibo odun 2015 to waye ni yii pelu aya re.
 Gege bi iwadii Olayemi Oniroyin lati enu awon to sun mo eni ti awon kan tun mo si Omi Tuntun. Won fi ye Olayemi Oniroyin wi pe, maanu naa ti gbagbe ijakule re ninu eto idibo to waye naa. Ati wi pe, igba tuntun to n bo ni ireti Seyi omo Makinde.
Eng Seyi niyii pelu iyawo re nibi won ti n sere lagbala.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...