Ooni tuntun ti lo fori bale niwaju pastor fun esin awon alawo funfun, eyi to tunmosi jesu oga ogo nile ijosin.
Awon kan ri gege bi ohun to ye fun eni to mo esin awon alawo funfun, sugbon awon kan ri gege bi fifi asa Yoruba wole.
Bawo le tiri?

Tagged with: ooni ile ife
Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀ A kìí gbélé ẹni ká fi ọrùn rọ́ ni a ti ń gbọ́ tipẹ́ tipẹ́, sùgbọ́n kín wá ni ká ti pe tirúfẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ ajániláyà yìí tó wáyé ní ààfin Ọọ̀nirìṣà Ọba Adéyẹyè Ògúnwùsì,ní alẹ́ ọjọ́ Ìṣẹ́gun níbi tí àwọn èèyàn ìlú Ilé Ifẹ̀ ni àwọn ti ń gbọ́ ìró ìbọn ní kíkàn kíkan ní ilé Oòduà tíí ṣe ààfin Ọọ̀nirìṣà Ilé Ifẹ̀, Ọba Adéyẹyè Ògúnwùsì . Eléyìí ló ṣì mú ...