Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà.
Omo egbé agbá bóòlù fún orílè èdè Nìjíríà tí na àwon omo egbé agbá bóòlú Cameroon ní méta sí Méjì, (3-2), ní gbàgede pápá ti Alexandria láti le wo ìpele kèta sí ife.
Jude Odion Ighalo ló gbá méjì wo ilé àwon alátakò won, tí Alex Iwobi sì gbá ìkan tí ó kùn wolé. Nse ni ó dàbí eni wípé òun ni yóò gba òdómokùnrin tó gbégbá orókè.
