Home / Àṣà Oòduà / Ìbon ba àwon ajínigbé nígbà tí won ń dúnà pàsípààrò lówó ní ìjoba ìpínlè Abia. 

Ìbon ba àwon ajínigbé nígbà tí won ń dúnà pàsípààrò lówó ní ìjoba ìpínlè Abia. 

Àwon ajínigbé mérin, èyí tí won ti ń da ìpínlè Abia àti agbègbè rè láàmú. Won ti ń gbìyànjú àti parun tí àwon òtelèmúyé so mó Omoba Division ní ojó ketàdínlógún osù keje (19th July ,2017) ní Ovungwu, Isiala -Ngwa ti Gúúsù Ìjoba ìbílè ìpínlè náà.
Àwon òdaràn yí ni ojó kejidínlógún osù keje odún 2017(18th July, 2017) ní Osisioma Ngwa fé fi ipá gbé arákùnrin kan tí ó ń jé Onyemaechi Mbamaonyeukwu Ijeoma ‘m’ tí ó jé Olùdarí ilé-isé Mba Hotel Aba ní inú okò rè tí ó jé Nissan Infinity Jeep tí ó jé àwò eérú pèlú Nómbà ìdámò rè GWA 807 DH  tí won sì gbà á sí inú ilé àkókùn kan ní Umuajuju Ovungwu, Isiala Ngwa ní gúúsù ìjoba ìbílè náà nígbà tí won ń dúnà pàsípààrò lówó…
 Nígbà tí won se èyí lówó, àwon òtelèmúyé tí ògá pátápátá DPO darí won, wo ààrin àwon ajínigbé yìí, gbàrà tí won rí àwon òtelèmúyé ni won bá bèrè sí ní yin ìbon. Nígbà tí won ń yin ìbon lówó méji nínú àwon ajínigbé tí a padà mò sí Nwadibia àti Monday ni ìbon pa tí àwon tókun sì bó pèlú ota ìbon l’ára won. Wón gba eni tí won nígbà kalè láì pa lára, ìkan lára àwon òtelèmúyé náà sì F’ara pa.
Àwon ohun tí a rí gbà padà ní, okò eni tí won jígbé yí tí ó jé Nissan Infinity Jeep, òkadà méjì àti èro ìbánisòrò mérin.
Ara òtelèmúyé tí ìbon bà ti ń m’ókun eni tí won jígbé náà ti lo bá àwon ebí rè, tí a ò sì tíì dáwó wíwá àwon òdaràn tí ó bó dúró….
Continue after the page break for English Version

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo