Aara meriri, egbani eleja, arabirin kan ti o un se agun ba ni ro so wipe olulu ipinle Enugu Ni Anambra, ati pe o tun so wipe, olulu ipinle Eko ni ilu Abuja. Eyin je oun ti o bani ninu je wipe akeko gboye ni ile eko giga, kuna lati so idaun si awon ibere won yin. English Version Continue after the page break