Awon eniyan oba ni Osupa ti mura tan lati gbe awo orin re tuntun jade. E le ka iroyin naa NIBI. Eniwee, mo sakiyesi wi pe awon aso okeere maa n mu oju osupa dabi odomode nigba ti awon aso ibile wa maa mu dabi baba agbalagba.

Tagged with: Saheed Osupa