Home / Àṣà Oòduà / Ifalodolu korowísí korowísí èmi…

Ifalodolu korowísí korowísí èmi…

Ifalodolu korowísí korowísí èmi na lodolu korowìsìkorowìsì baba mi agbonmniregun baba mi elesin-oyan mo ni ao ri wu oba ba won yiri oba tojoba tan lalede orun odele aye tan oda osere oun egbe le oloun opa iru omo eku run oloun opa iru omo eja run iru omo eye run iru omo eran run iru omo esin run iru omo eni run iru eku komara iru eja komara iru eye komara iru eran komara iru esin komara iru awa eniyan kamamara o ejielemere gbawa o ifa gbawa mojeki isese oparun mojeki awa na parun lode isalu aye iwo na sotie

ifa said it turn 2 olukorowisi korowisi and me too i said it turn 2 olukorowisi korowisi my father the agbonmniregun my father the coch event i hav not seen  the type of king like this the king in heaven and he wnted to destroy such mice such fish such bird such goat such horse such people such mice such fish such bird such goat such horse such people shall not destroy pls ejielemere help us ifa help us dnt let tradition be destroyed and don’t me and my people be destroyed too wot of u type ur own.

By Ifaniyi Ifadamilare

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

ifa

Kùtùkùtù Ìrèní Laó He Erè Nígbódù Oòni

Òní laó roko létí opónÒla laó sákà lágbèrùKùtùkùtù ìrèní laó he erè nígbódù oòniKáyáa múlé pontíKámú òdèdè rokàKáfi agbada dínranÀwèje wèmu nípón omodé wòyí lójúÒrìsà lópabuké tánLódákún sábaro nídìíOmo-ojo húnsáré gíríjo-gíríjoOmo-ojo húnsáré gìrìjo-gìrìjoIlé-ifón kògba obàtáláÈlàgboro kògba òrìsàOjúgboro ni tàfínÈlàgboro ni tòrìsàOmi níti ojú-omi rúwáÈròyà wáàponÈròyà wáàmuRúkú-rùkù-rúkú niwón nse lókè ohùnkòErú kùnrin won nííjé bánakúErú bìnrin won nííjé wòrúkúDimúdimù aleìgbòOkùnrin yàkàwú orí ìgbáÌgbá kòwóOkùnrin yàkàwú kòsòkalèÒní laóko igbó olú-kóókó-bojoÒla laóko igbó olú-kóókó-bojoAkogbó olú-kóókó-bojo tánApa ekùn kan mìnììjò-miniijo tínbe lábé ìtíWónní kí ...