Home / Àṣà Oòduà / Ìrosùn Méjì

Ìrosùn Méjì

Whoever this Odu is revealed to maybe during Ifá consultation, ìtènifá or Ìséfá, this person needs to offer Ebo and feed Ifa.
One of the biggest problem of this person is lack of wealth. This person complains alot about not having money, people’s respect and honor. He/she need to offer Ebo very well but Ifa warns this person to always appreciate things and should stop the habit of saying negative words to themselves.
Ifa advice this person to offer Ebo and feed Ifa with one big Pig in other to have lot of Ire and peace of mind.
The Ifa goes thus:
Lásánlásán ni Olósùn mejì s’ojú Lásánlásán
Bí eni tó ló’ró nínú
Béè n’Ìrosùn Méjì ò n’íkà nínú
Díá fún Olósùn Méjì
Tó f’èyìn, tó m’ójú ekún sùnráhùn Ire gbogbo
Ebo ni Wón ní kó wá se
Ó gb’ébo, ó rúbo
Aládé wá f’elédè rú’bo
Gbèdè, Lara ó ma dè wá lo, Gbèdè
Gbèdègbede níí ro igbá epo
Gbèdègbede níí ro igbá òrí.
Translation
Ordinarily, Olósùn Méjì looks like a wicked person
But Ìrosùn Méjì harbors no wicked thoughts
This was the declaration of Ifá to Olósùn Méjì
When he was lamenting his inability to have all the Ire of life
He was advised to offer Ebo
He complied
Aládé has offered Ebo with a Pig
With ease shall we be blessed with all Ire and comfort
A calabash filled with palmoil will never experience hardship
A calabash filled with Shea butter will never experience hardship.
Àború Àboyè!!!
~Owo

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

ifa

Kùtùkùtù Ìrèní Laó He Erè Nígbódù Oòni

Òní laó roko létí opónÒla laó sákà lágbèrùKùtùkùtù ìrèní laó he erè nígbódù oòniKáyáa múlé pontíKámú òdèdè rokàKáfi agbada dínranÀwèje wèmu nípón omodé wòyí lójúÒrìsà lópabuké tánLódákún sábaro nídìíOmo-ojo húnsáré gíríjo-gíríjoOmo-ojo húnsáré gìrìjo-gìrìjoIlé-ifón kògba obàtáláÈlàgboro kògba òrìsàOjúgboro ni tàfínÈlàgboro ni tòrìsàOmi níti ojú-omi rúwáÈròyà wáàponÈròyà wáàmuRúkú-rùkù-rúkú niwón nse lókè ohùnkòErú kùnrin won nííjé bánakúErú bìnrin won nííjé wòrúkúDimúdimù aleìgbòOkùnrin yàkàwú orí ìgbáÌgbá kòwóOkùnrin yàkàwú kòsòkalèÒní laóko igbó olú-kóókó-bojoÒla laóko igbó olú-kóókó-bojoAkogbó olú-kóókó-bojo tánApa ekùn kan mìnììjò-miniijo tínbe lábé ìtíWónní kí ...