E MAA WI TELE MI :
………
*Osu karun-un yii, osu ire owo ni fun mi.
*Osu ire ile kiko ni fun mi.
*Osu ti maa ra oko ayokele.
*Osu igbega lenu ise mi ni.
*Osu idunnu ni yoo je fun ni.
*Osu aseyori mi ni.
*Osu ayo mi ni.
*Emi ni oloriire akoko ninu osu yii(Ase Edumare).
……….
E ku ojulona IBILE FESTIVAL SEASON1 #IFS.
……….
Ijo ibile.
Ilu ibile.
Orin ibile (Ewi, Ijaala, Esa).
Iwosan ibile.
Ounje ibile.
Aso ibile.
Iwo naa le wa soju ilu re pelu ounje ati nnkan ibile ilu re, nibi ayeye #IBILE2016.
Tagged with: Iwure