Iyawo Oloju Buluu Posted by: baileygage505 in Àṣà Oòduà, Iroyin Pajawiri Comments Off on Iyawo Oloju Buluu ‘Kìí ṣe tìtorí owó ni mo ṣe fẹ́ gba Risikat padá, mo ní ìfẹ́ ẹ rẹ̀ ni ‘ Wasiu Jimoh, ọkọ Risikat tó ní ojú búlúù ní Ilọrin bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀, ìyàwó rẹ̀ náà fèsì. Iyawo Oloju Buluu Ẹ wá gba ohun tí wọ́n wí. iyawo 2020-08-19 baileygage505 tweet