Home / Àṣà Oòduà / Ekale ooo!!! Kin ni oruko ti a n’pe iwu ilu yi ni ile Yoruba?

Ekale ooo!!! Kin ni oruko ti a n’pe iwu ilu yi ni ile Yoruba?

Gbogbo eyin apapo olorire lagbaiye mini ile nla I.K.O. NLA wayi o lawujo apapo awon ojogbon awo mimo
Fun idanileko Lori ASA ile wa
Opolo eni kokan wa koni di oku o
Ifa koni kuru lakaye eni kokan wa o
Ejowo too
Fun idanileko na fun gbogbo eyin olorire lagbaiye
Kin ni oruko tiama npe iwu ilu yi ni ile Yoruba wa yi oo

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára