Home / Àṣà Oòduà / Kò kò, ó gbà láti se ètùtù, Moronke Naomi Oluwaseyi gbà láti se òun tótó gégé bí olorì àkókó láàrin àwon olorì pátápátá.

Kò kò, ó gbà láti se ètùtù, Moronke Naomi Oluwaseyi gbà láti se òun tótó gégé bí olorì àkókó láàrin àwon olorì pátápátá.


Bí won se ni kó se é ló se é. Bí ó tilè jé wípé àtúnbí nínú Jésú ni, kò kò láti se àwon ohun tí ó tó gégé bí olorì láàfin Oòni ti ilé-ifè.
Àwòrán ibi tí ìyàwó ti n se àwon ètùtú tí ó ye, tí ó sì dá èjè kojá.
Àdúrà wa ni wípé: kí olorì tuntun bí obìnrin àbíró, Okùnrin àbíyé (Àse).
Ó ti se é se..

About Awo

One comment

  1. Been a Queen is important to her generation but doing the neccesary things is importanter…
    #prophetess turn to a Queen

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo