Oun tí ó ba ni nínújé gbáà ni ìsìnkú okùnrin kan pèlú ìyàwó rè àti omokùnrin won tí ó kú ní ojó kan náà. A gbó wípé ojó kan náà ni won ma sin wón ní ìpínlè Imo. Èyí mà le Ooo..
Home / Àṣà Oòduà / Òbísúárì okùnrin kan, ìyàwó rè pèlú omokùnrin won tí a gbó wípé won sin won ní ojó kan náà .
Tagged with: Àṣà Yorùbá