Òdókùnrin kan tí a gbó wípé ó jé omo ogún odún ni a gbó wípé won fi èsùn kàn àwon olópàá Látàrí ìbon tí won yìn pa Òdókùnrin yí, nígbà tí won ń parí ìjà lówó láàrin àwon ìkò ológun méjì ní agbègbè Ajegunle ní ìpínlè Èkó. Kí olórun te sí aféfé rere.

Tagged with: Àṣà Yorùbá
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...