Home / Àṣà Oòduà / Òdókùnrin kan ní àwon olópàá yin ìbon pa nígbà tí won fé parí ìjà ní Ajegunle.

Òdókùnrin kan ní àwon olópàá yin ìbon pa nígbà tí won fé parí ìjà ní Ajegunle.

Òdókùnrin kan tí a gbó wípé ó jé omo ogún odún ni a gbó wípé won fi èsùn kàn àwon olópàá Látàrí ìbon tí won yìn pa Òdókùnrin yí, nígbà tí won ń parí ìjà lówó láàrin àwon ìkò ológun méjì ní agbègbè Ajegunle ní ìpínlè Èkó. Kí olórun te sí aféfé rere.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?